Fọ́mù Iforukọsilẹ Akẹkọ

Page 1

Àwọn Ìtọ́ni:  Jọwọ ṣe àkọpari gbogbo awọn àlàfo nísàlẹ̀ yìí.

Iwífún-ni AkẹkọDéti Ọjọ Ìbí

Indy Reads ń ṣiṣẹ́ fún àwọn àgbà akẹ́kọ̀ọ́ ní ìpínlè Indiana. Jọ̀wọ́ kọ orílẹ̀-èdè rẹ, tó bá sì yẹ, kọ ìpínlẹ̀ àti ìlú rẹ sí ìsàlẹ̀. A yó lo ohun tí o fi sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi dátà láti wo bó ṣe ṣeéṣe sí kí á tan ètò wa ká àwọn agbègbè mìíràn. O ṣé!
Ipele Ètò Ẹkọ
    


Ipò Ọ̀daràn Rí-Ipò Ìtọjú/Imúpadàbọ̀sipò

Page 2

Àwọn Ifojúsùn